Zola Nombona | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 10 Oṣù Kẹta 1992 Mthatha, Eastern Cape, South Africa |
Orílẹ̀-èdè | South African |
Ẹ̀kọ́ | Victoria Girls' High School |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of the Witwatersrand |
Iṣẹ́ | actress |
Ìgbà iṣẹ́ | 2013–present |
Àwọn ọmọ | 1 |
Zola Nombona (bíi ni ọjọ́ kẹwàá oṣù kẹta ọdún 1992[1]) jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè South Áfríkà tí ó gbajúmọ̀ fún ipá Shado tí ó kó nínú eré Intersexions ni ọdún 2013.[2] Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Victoria Girl's High School no ìlú Grahamstown kí ó tó wà lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Wits University níbi tí ó tí gboyè nínú ìmò Dramatic Arts.[3][4]
Nombona kọ́kọ́ kópa nínú eré Intersexion ní ọdún 2013, eré náà si sọ̀rọ̀ nípa àrùn kogboogun HIV/AIDs. Ní ọdún 2015, ó kó ipa Roxanne nínú eré Zbondiwe.[5][6] Ó kọ ipa Monde nínú eré Lockdown àti Zee nínú eré Number Number.[7]
Ọdún | Àkọ́lé | Ipa tí ó kó |
---|---|---|
2015 | Ingoma | |
Forced love | Kat Minola | |
Number Number | Zee | |
iThuba lokugcina | Zodwa Bhengu | |
2018 | Lockdown | Monde |
2019 | EHostela | Constable Brightness |