Zenande Mfenyana | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Zenande Feziwe Mfenyana 11 Oṣù Kẹ̀wá 1985 Kagiso, Gauteng |
Orílẹ̀-èdè | South Africa |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Pretoria (BA in Drama) |
Iṣẹ́ | Actress |
Ìgbà iṣẹ́ | 2006–present |
Notable work | Generations |
Zenande Mfenyana (bíi ni ọjọ́ kọkànlá oṣù kẹwàá ọdún 1985[1]) jẹ́ òṣèré àti mọ́dẹ́lì ni orílẹ̀ èdè South Áfríkà. Ó gbajúmọ̀ fún ipá Noluntu Memela tí ó kó nínú eré Generations. Wọ́n bíi Mfenyana sì ìlú Johannesburg. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Queenstown Girl's High School kí ó tó tẹ̀ síwájú sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí University of Pretoria níbi tí ó tí gboyè nínú ìmò Dírámà.
Mfenyana di gbajúmọ̀ ni ọdún 2011 fún ipá Noluntu Memela tí ó kó nínú eré Generations èyí tí Mfundi Vundla gbé jáde.[2] Ní oṣù kìíní ọdún 2015, ó kó ipa Reba nínú eré Ashes to Ashes pẹ̀lú àwọn gbajúmọ̀ òṣèré bíi Tina Jaxa àti Menzi Ngubane.[3] Ní oṣù kejì, ọdún 2017, ó kó ipá Goodness Mabuza nínú eré The Queen.[4]
Odun | Akori ere naa | Ipa ti o ko | |
---|---|---|---|
Generations | Noluntu Memela | ||
Ashes to Ashes | Reba Namane | ||
Igazi[5] | Babalwa | ||
MTV Shuga (Down South) | Cynthia Vilakazi | ||
2017 | The Queen | Goodness Mabuza |