Yakubu Muhammed | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 25 Oṣù Kẹta 1973 Bauchi, Nàìjíríà[1] |
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Ẹ̀kọ́ | Mass Communication (BSc) |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Jos, Bayero University Kano[2] |
Iṣẹ́ | Film Actor, producer, director, Singer,[3] Script Writer |
Ìgbà iṣẹ́ | 1998–present |
Gbajúmọ̀ fún |
|
Yakubu Mohammed tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n oṣù Kẹ́ta ọdún 1973 jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé, olùgbéré-jáde, adarí eré, olórin àti olùkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó tún jẹ́ aṣojú àti olùpolówó ọjà fún ilé-iṣẹ́ ìbáraẹni sòrò ti Globacom.[4] Ó tún jẹ́ aṣojú fún àjọ SDGs , ó sì tún fìgbà kan jẹ́ aṣojú fún ilé-iṣẹ́ ambassador and Nescafe Beverage.[5] Yakubu Mohammed jẹ́ ọ̀kan lára àwọn lààmì-laaka ní Kannywood àti Nollywood. Ó ti kọ orin tí ó ti lé ní ẹgbẹ̀rùn ún, ó ti kópa nínú eré rí ó ti tó ọgọ́rùn ún nínú eré Hausa. Lára rẹ ni: Lionheart, 4th Republic, Sons of the Caliphate àti MTV Shuga èyí tí ó sọọ́ di ẹni tí wọ́n fún àwọn amì-ẹ̀yẹ ọlọ́kan-ò-jọkan bí City People Entertainment Awards[6] àti Nigeria Entertainment Awards.
kannywood ni Yakubu ti bẹ̀rẹ̀ ìkòpa nínú eré ní ọdún 1998 nígbà tí ó kọ eré kan tí ó sì ṣe agbátẹrù eré náà. Nígbà tí ó yá, ó kẹ́kọ̀ọ́ síwájú si nínú iṣẹ́ tíátà, tí ó sì gòkè àgbà nínú iṣẹ́ tí ó yàn láàyò. Yakubu tún jẹ́ olórin tí ó sì ti gbé orin tí ó tó ẹgbẹ̀rún kan jáde fún àwọn eré sinimá àgbéléwò lọ́kan ò jọ̀kan àti àwọn mìíràn ní èdè Hausa àti Gẹ̀ẹ́sì, [7][8] òun àti ọ̀rẹ́ rẹ̀ tí wọ́n jọ ń ṣiṣẹ́ pọ̀ Sani Musa Danja. Ó dara pọ̀ mọ́ Nollywood ní ọdún 2016 nígbà tí ó ṣe Sons of the Caliphate pẹ́lú Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ akẹgbẹ́ rẹ̀ kan Rahama Sadau[9] Ó tún fara hàn nínú àwọn eré bíi: MTV Shuga àti Lionheart.[10]
Àkọ́lé | Ọdún |
---|---|
Sons of The Caliphate[11] | 2016 |
MTV Shuga Naija[12] | 2017 |
Queen Amina[13] | |
Makeroom[14] | |
LionHeart[15] | |
Asawana | |
4th Republic[16] | |
Tenant of The House[17] | |
Dark Closet[18] | |
Fantastic Numbers[19] | |
Walking Away[20] | |
My Village Bride[21] | |
Chauffeur[22] | |
Damaged Petals[23] | |
Bunmi's Diary[citation needed] | |
Power of Tomorrow[24] | |
My Neighbor's Wife[25] | |
My Wife's Lover[26] | |
Blue Flames[27] | |
April Hotel[28] | |
Women | |
Wings of A Dove[29] |
Cikin Waye | ND |
Gabar Cikin Gida | 2013 |
Da Kai Zan Gana | 2013 |
Mai Farin Jini | 2013 |
Nas | 2013 |
Romeo Da Jamila | 2013 |
Sani Nake So | 2013 |
Shu'uma (The Evil Woman) | 2013 |
Soyayya Da Shakuwa | 2014 |
So Aljannar Duniya | 2014 |
Sai A Lahira | 2014 |
Munubiya | 2014 |
Hakkin Miji | 2014 |
Duniyar Nan | 2014 |
Bikin Yar Gata | 2014 |
Kayar Ruwa | 2015 |
Son of Caliphate | 2016 |
Hawaye Na | 2016 |
Yar Mulki | 2016 |
Àdàkọ:Authority control