Thishiwe Ziqubu | |
---|---|
Thishiwe Ziqubu n soro nipa sise oludari MTV Shuga ni odun 2019 | |
Ọjọ́ìbí | 5 August 1985 |
Orílẹ̀-èdè | South Africa |
Iṣẹ́ | oludari ere ati osere |
Thishiwe Ziqubu (ti a bi ni ojo karun osu kejo odun 1985) je ako ere, oludari ere ati osere ti owa lati ilu South africa.[1] Won gba ami eye Best Actress in a Supporting Role ni 2016 Africa Movie Academy Awards , fun ipa won gege bi Tashaka ninu ere ife Tell Me Sweet Something.[2] Ni odun 2019, won shey oludari awon ipele kankan ninu MTV Shuga Down South [3]
Ziqubu keko nipa kiko ere ati pelu bi a se man dari ere lehin ti o pari ile iwe giga. Lehin na won lo si ile eko African Film and Drama Academy (AFDA), ile eko nipa fiimu[4]. Lehin wa igba na won pari eko nipa sisere ni Los Angeles campusi titi New York Film Academy.[1]
Ziqubu bere ere sise ni odun 2011 ni pase fiimu Man on Ground, eleyi ti o je ki ise ise re sun si waju. Gegebi onkowe ati oludari ere, won ko, won si tun gbe ere kukuru meta jade fun ra won awon fimmu na ni: Out Of Luck, Subdued ati Between the Lines.[1]. Won ti ko ere fun awon fiimu South African television soap opera gege bi Isidingo, Rhythm City ati fun Is'Thunzi . Won ko pa ninu kiko, gbigbejade ati didari supernatural ere dirama eleya merin ti a mosi Emoyeni.[5]
Ni odun 2019, won shey oludari ere elesese MTV Shuga Down South.
Year | Title | Role |
---|---|---|
2011 | Man on Ground | Zodwa |
2014 | Hard to get | Skiets[6] |
2015 | While You Weren't Looking | Shado |
2015 | Tell Me Sweet Something | Tashaka |