Terry Pheto
Ọjọ́ìbíMoitheri Pheto
11 Oṣù Kàrún 1981 (1981-05-11) (ọmọ ọdún 43)
Evaton, South Africa
Iṣẹ́Actress
Ìgbà iṣẹ́2005–present

Moitgeri Pheto (bíi ni ọjọ́ kọkànlá oṣù karùn-ún ọdún 1981) jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè South Áfríkà, ó gbajúmọ̀ fún ipá Miriam tí ó kó nínú eré Tsotsi[1]

Iṣẹ́

Lẹ́yìn farahàn nínú ere Tsotsi, Pheto tí kópa nínú orísìírísìí eré míràn bíi Catch a Fire(2006), Goodbye Bafana (2007) àti How tó steal 2 Million (2012). Ni oṣù keje ọdún 2008, òun ni ó ṣe ojú fún L'Oréal. Ó ti farahàn nínú orísìírísìí ìwé ìròyìn bíi Destiny, Vanity Fair, Drum, You/Huisgenoot, Y-Magazine, Bona, Heat, Elle, Cosmopolitan, Marie Claire ati True Love. Ó gbà ẹ̀bùn láti ọ̀dọ̀ Africa Movie Awards.[2]

Àṣàyàn àwọn eré rẹ̀


Àwọn itọkasi