Neveen Dominic | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | South Sudan |
Iṣẹ́ | Osere, agbere jade, onisowo ati oninurere |
Neveen Dominic je osere, agbere jade, onisowo[1]
ati oninurere ti o wa lati Gúúsù Sudan ti on gbe ni ilu Kánádà.[2]
Ilu South Sudan ni wwon bi Dominic si. Oni oselu ni baba e[3] iya e si je osere.[4]Ni igba ti o wa ni omo odun medogun ohun ati awon molebi re ko lo si ilu Calgari, Kanada nigba ti ogun waye ni ilu Sudan.[5] Ni osu kakanla odun 2019, ohun ati oko re, omo ilu Nàìjíríà kan ti on gbe ni ilu Kanada[6], bi omo akoko wan.[7]
Dominic je osere omo South Sudan akoko ti o ko ipa ninu fiimu ilu Naijiria Nollywood.[8] O hun lo se igbejade fiimu jara nollywood ti amo si "It's A Crazy World" o ko ipa ninu ere na. Ni osu keta odun 2019, Eagle Online so wipe on gbero lati pada si enu jara na ni ilu Naijiria.[9] Lehin ti o pada wa, o gba awon osere Nollywood nlanla se ere, awon osere bi Bob-Manuel Udokwu, Amanda Ebeye, Grace Amah, Moyo Lawal, Francis Odega, Tunbosun Aiyedehin, ati Tochi Ejike Asiegbu ninu jara titi Nollywood.[10]
Ohun lo se eto atike olorin ni ose asa ati oge titi New York ni odun 2018, fun Glenroy March[11]
Ohun ni oluda sile Neveen Dominic Cosmetics, ti o wa ni ilu Calgary, Alberta, Kanada ti ile iise ero won wa ni United States ati Jẹ́mánì.[12] Ni osu kerin odun 2019 o kede pe ohun o ma ta oja ohun ni ilu Naijiria ati Ghánà .[13][14][15]
Ninu itan-akoole ti ara eni ti akori e je "Beauty From The Ashes of War" o so itan aye e gegebi alasasala ti o wa lati South Sudan, o si sope ile ise oge ohun je fun igbiyanju awon obinrin.[16]
Ni asiko ajakale arun COVID-19, o se agbekale bi oti ma fun awon eyan e egberun marun ni ounje. Iwe iroyin Leadership ni o so wipe.
"...mo ti lo si ilu Naijiria fun ise kan, esekese ni mo feran bi awon odo se feran owo sise ni ilu na,ni tori eyi ni mo fe fi bun awon eyan ni owo''[17][18]