Mmabatho Montsho (bíi ni ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù kẹwàá ọdún 1983) jẹ́ akọ̀wé, òṣèré àti adarí eré fíìmù) ni orílẹ̀ èdè South Áfríkà.[1][2][3][4][5]
Wọ́n bíi sì ìlú Soweto. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Greenside High School kí ó tó tẹ̀ ṣíwájú sì ilẹ̀ ẹ̀kọ́ gíga tí University of South Africa níbi tí ó tí gboyè nínú ìmò Audio-visual Multimedia. Ní ọdún 2006, ó bẹ̀rẹ̀ eré ṣíṣe. Eré tí ó kọ́kọ́ ṣé ni A place called Home.[6] Ó gbà àmì ẹ̀yẹ Best Achievement in Script in a TV Drama láti ọ̀dọ̀ Golden Horn Award.[7] Ní ọdún 2020, ó gbà àmì ẹ̀yẹ fún eré ránpẹ́ tí ó dára jù lọ láti ọ̀dọ̀ Worldwide Women's Film Festival.[8][9]