Lesego Motsepe | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 28 Oṣù Kẹrin 1974 |
Aláìsí | 20 January 2014 Randburg, Gauteng[1] | (ọmọ ọdún 39)
Iṣẹ́ | Actress |
Lesego Motsepe (bíi ni ọjọ́ kejìdínlógbọ̀n oṣù kẹrin ọdún 1975) jẹ́ òṣèré àti olórin ni orílẹ̀ èdè South Áfríkà[2] tí ó gbajúmọ̀ fún ipá Letti Matabane tí ó kó nínú eré Isindigo láti ọdún 1998 títí di ọdún 2008[3]. Ó jáde láti sọ̀rọ̀ ní ọdún 2011 pé òhun ní àrùn kogboogun HIV.[4] O dàgbà sì ìlú Meadowlands, ó sì lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Technikon Pretoria níbi tí ó tí gboyè nínú ìmò ọ̀rọ̀ sísọ àti dírámà. Ní ìgbà tí ó wà ní ọmọ ọdún márùn-ún, ó kópa nínú ìpolówó lórí tẹlẹfíṣọ̀nù, ibè sì ni wọn ti fún ní orúkọ inagi Nama Ya Nku. Ó kópa eré Biko - Where the Soul Resides .