Henrietta Mbawah | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Henrietta Mbawah Sierra Leone |
Orílẹ̀-èdè | Sierra Leonean |
Iṣẹ́ | Actress, director, social activist |
Ìgbà iṣẹ́ | 2000–present |
Henrietta Mbawah jẹ́ òṣèré àti ajìjàgbara lórílẹ̀-èdè Sierra Leone.[1][2] Ó gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bí olùdarí eré eré Jattu àti fún ipa tí ó kó nínú eré Ebola Checkpoint.[3][4]
Ní ọdún 2016, Mbawah gbé eré rán pé Jattu kalẹ̀. Eré náà sọ̀rọ̀ nípa ọmọbìnrin Jattu tó ṣẹ́gun àrùn Ebola ní Áfríkà. Ní ọdún náà, ó kó ipa oníróyìn nínú eré Ebola Checkpoint[5]. Òun ni olùdarí Manor River Entertainment Company[6]. Ní ọdún 2019, ó gbà àmì ẹ̀yẹ Sister's Choice Award.[7]