Fatiha Berber (odun 1945 titidi odun 2015) je esere omo ilu Àlgéríà ti atun mosi Fatiha Blal.

Igbesiaye

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A bi Fatiha Berber ni Casbah of Algiers.[1] A won molebi re wa lati Legata ni Boumerdès Province titi apa ariwa ilu Algeria.[2]

Ni odun 1950 okorin pelu awon Meriem Fekkaï, lehin igba na olo ko eko drama ni Conservatory of Algiers. Oludari Mustapha Gribi fun ni ipa e akoko ninu ere Molière, Les femmes savantes. Oko ipa ninu Algeria's National Liberation struggle.

O se alaisi ni ojo kerindinlogun osu kini ni odun 2015 ni pa se arun okan.[3][4]

Awon Ise

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Awọn fiimu

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Tẹlifisiọnu jara

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Awọn itọkasi

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Cinéma: L'actrice algérienne Fatiha Berber n'est plus, Huff Post, 16 January 2015
  2. Yacine Idjer, Fatiha Berber: Une étoile s'est éteinte, DjaZairess, 17 January 2015.
  3. Cinéma: L'actrice algérienne Fatiha Berber n'est plus, Huff Post, 16 January 2015
  4. Yacine Idjer, Fatiha Berber: Une étoile s'est éteinte, DjaZairess, 17 January 2015.