Deolinda Kinzimba | |
---|---|
Kinzimba ni odun 2017 Kinzimba ni odun 2017 | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Deolinda Inês Caetano Kinzimba |
Ọjọ́ìbí | 11 Oṣù Kàrún 1995 Luanda, Angola |
Irú orin | Pop, rhythm and blues, soul |
Occupation(s) | Akorin, Osere |
Instruments | Ohun |
Years active | 2015–titi di isinyi |
Deolinda Inês Caetano Kinzimba (ti a bi ni ọjọ kankanla Oṣu Karun Odun1995) jẹ ọmọ ilu Angola ti o je akọrin ati oṣere.
Ilu Luanda ni won bi Kinzimba si, sugbon odagba ni Ingombota. O so wipe ohun lo igba omode ti odun, ati pe ati kekere ni toi feran orin. Awon ti oman wo awokose won ni Phyllis Hyman ati Selena Quintanilla.[1] Ilu Tanzania ni o gbe gegebi owe, nitori o ni egbon obinrin ti on sise ni ile ise asoju Àngólà. O ko lo si Guimaraes, ni ile Portugal lati ni ojo iwaju ti o dara. Kinzimba ko eko imo ofin ni Porto.[2]
Ni odun 2016, o bori ninu ipele keta titi The Voice Portugalti o waye ni Kinzimba, won tun pe ni Whitney Houston titun nitori oko orin Whitney Houston, I Have Nothing. Otun ko orin "I Will Always Love You" ti Mariah Carey ko ati "A Moment Like This" ti Kelly Clarkson ni igbeyin idije na. Ohun ati iya eh tunrari lehin ti won wa ni yiya fun odun meji.[3]Ni tori oje olubori idije yi, o se ifowobowe pelu Universal.[4] Ni osu kewa odun 2016, o ko ipa ninu eto "Dentro".[5]
Orin akoko eh je "Primeira Vez" ti ojade ni osu kewa odun 2016[6] Ni osu kankanla odun 2017, o fi awo orin re kale, eyi ti akori re je oruko e.[7]Awo orin yi gba irawo meta ati abo ni owo Sábado, o gbe ori yin fun Kimzimba fun awon ise takun takun ti ose lori awo orin na[8]. O ko ipa ninu ajodun RTP da Canção 2017, Rita Redshoesni o gba ni alejo ni eto na, osi de eyin eto na.[9]