Beverly Osu | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Beverly Ada Mary Osu 27 Oṣù Kẹ̀sán 1992 Lagos State, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Babcock University and National Open University of Nigeria |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 2011-Present |
Beverly Ada Mary Osu tí wọ́n bí ní ọjọ́ Kẹtàdínlọ́gbọ̀ oṣù Kẹjọ ọdún 1992 (September 27,1992) jẹ́ alájótà oníhòhò ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1] ó di ìlú mọ̀ọ́ká lórí àwọn ipa rẹ̀ ní oríṣiríṣi sinimá àti ipa tí oko ní inú Big Brother Africa ẹlẹ́kẹjọ Irú rẹ̀.[2][3] Ó gba àmì-ẹyẹ ti Dynamix All Youth Awards ti ọdún 2011.[4]
Osu, jẹ́ ọmọ ìpínlẹ̀ Delta àmọ́ tí wọ́n bí sí Ìpínlẹ̀ Èkó.[5] Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ Daughters of Divine Love Convent, tí ó wà ní Ìpínlẹ̀ Enugu, nígbà tí ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ Fásitì Babcock, láti kẹ́kọ̀ọ́ gboyè àkọ́kọ́ nínú ìmọ̀ Ibà ọ̀pọ̀ ènìyàn sọ̀rọ̀ (mass communication), àmọ́ kò parí níbẹ̀. Ẹ̀wẹ̀, ó darí ẹ̀kọ́ rẹ̀ sí National Open University of Nigeria láti parí ìkẹ́kọ́ gboyè rẹ̀ láti ilé-ẹ̀kọ́ Fásitì Babcock. [6] .[2][7]