Beverly Naya | |
---|---|
Naya on NdaniTV in 2018 | |
Ọjọ́ìbí | Beverly Ifunaya Bassey 17 Oṣù Kẹrin 1989 London, England, United Kingdom |
Iṣẹ́ | Actress |
Ìgbà iṣẹ́ | 2008–present |
Beverly Naya (tí àbísọ rẹ̀ jẹ́ Beverly Ifunaya Bassey; tí wọ́n bí ní 17 Oṣù Kẹẹ̀rin Ọdún 1989) jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì. Ó gba àmì-ẹ̀yẹ ti òṣèré tí ó ní ìlérí jùlọ níbi ayẹyẹ Best of Nollywood Awards ti ọdún 2010. Ó tún gba àmì-ẹ̀yẹ òṣèrébìnrin tó yára tayọ jùlọ níbi ayẹyẹ City People Entertainment Awards ti ọdún 2011.[1][2][3]
Ìlú Lọ́ndọ̀nù ni wọ́n bí Beverly sí, ó sì jẹ́ ẹyinjú àwọn òbí rẹ̀.[4] Ó bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣe iṣẹ́ òṣèré nígbà tí ó n kàwé lọ́wọ́ ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga Brunel University ní ọmọ ọdún mẹ́tàdínlógún. Ó kẹ́kọ̀ọ́ kíko ìtàn-eré láti ilé-ẹ̀kọ́ gíga Roehampton University.[5] Ó tọ́ka sí Ramsey Nouah àti Genevieve Nnaji gẹ́gẹ́ bi àwọn àwòkọ́ṣe rẹ̀.[6]
Ó bẹ̀rẹ̀ eré ṣíṣe ní ọmọ ọdún mẹ́tàdínlógún. Ní ọdún 2011, Wọ́n mu gẹ́gẹ́ bi òṣèrébìnrin tó yára tayọ jùlọ níbi ayẹyẹ City People Entertainment Awards. Nígbà tí wọ́n bií léèrè ìdí tí ó fi padà wá sí Nàìjíríà, ó fèsì lédè gẹ̀ẹ́sì báyìí wípé:
"After I graduated from university, I just knew that I wanted to act, I knew I wanted to act, and in London I could shoot a film probably once in a year and that's it. Whereas coming to this industry, I can build a brand as well as shoot films more often and be given a more diverse amount of scripts. So, I decided to come back for that reason"[7]
Ọdún | Ayẹyẹ | Ẹ̀ka | Iṣẹ́ eré | Èsì |
---|---|---|---|---|
2014 | ELOY Awards[10] | TV Actress of the Year | Tinsel | Wọ́n Yàán |
2011 | City People Entertainment Awards[11][12][13] | Fast Rising Actress | Gbàá | |
2010 | 2010 Best of Nollywood Awards | Most Promising Talent | Gbàá | |
2020 | Africa Magic Viewers' Choice Awards (AMVCA) | Best Documentary | Skin | Gbàá |
|url-status=
ignored (help)
|url-status=
ignored (help)
|url-status=
ignored (help)